Wednesday, 1 January 2014

ECWA Choir Yoruba Mushin Enitojoko (Psalm 91)

The lyrics of the song in Yoruba is as written below:

Eni to joko ni ibi ikoko oga ogo
Ni yo ma gbe abe ojiji eledumare
Awa yo wipe o, Olorun ni abo wa
Haa, Olorun wa, Olorun o, ti a gbekele

Jesu ni abo awon togbekele
O ti gbewaga ori apata
Iji aye koni le mi ayanfe
Ati sa sodo Jesu
Abo wa nigba iji fe

Eni to joko nibi ikoko Olorun Baba
Ni yo ma gbe abe ojiji Jesu Kristi
Olorun yi o gbawa o, ninu kekun awon peyepeye
Haa, Oluwa ni yo se abo atodi aye wa

Eni to joko nibi ikoko Jesu Oluwa
Ni yo ma gbe abe ojiji Olorun o
Egberun yi o subo o, ni otun atosi wa
Haa, Oluwa ni yo se abo atodi aye wa

Eni to joko ni ibi ikoko oga ogo
Ni yo ma gbe ninu ayo Olorun o
Buburu kan o, koni subulu wa rara
Haa, Olorun ni iyo se abo ati igbekele wa

Alagbara
Oba to lagbara ni a romo (lawa romo Baba)
Oba to lagbara ni a dimu o (lawa dimu o)
Jesu Olugbala ni a gbagbo o (atofarati)
Olorun iyanu ni koni doju tiwa

Alagbara
Oba to lagbara ni a romo (lawa romo Baba)
Oba to lagbara ni a dimu o (la dimu o)
Jesu Olugbala ni a gbagbo o (atofarati)
Olorun iyanu ni koni doju tiwa

Alagbara
Oba to lagbara ni a romo (olorun iyanu)
Oba to lagbara ni a dimu o (la dimu o)
Jesu Olugbala ni a gbagbo o (lagbagbo)
Olorun iyanu ni koni doju tiwa

The song is translated in English as:

He that dwells in the secret place of the most High
Will abide under the shadow of the Almighty
Will say, The Lord is a refuge, Our God in whom we trust

Jesus is a refuge for those who trust in Him
He has lifted us on top of the mountain
The storms of life will not shake His beloved
We have run to Jesus
Our shield in times of storm

He that dwells in the secret place of our Father God
Will abide under the shadow of Jesus Christ
God will deliver us from the snares of the fowler
The Lord will be the refuge and fortress of our life

He that dwells in the secret place Jesus Lord
Will abide under the shadow of God Almighty
A thousand will fall at our right and lefthand side
But the Lord will the a refuge and fortress for our lives

He that dwells in the secret place of the most High
Will abide in the joy of the Lord
No harm shall befall us
For the Lord will be our refuge and trust

The powerful God
We lean on a powerful King
We hold on to a powerful King
Jesus, the Saviour, is He we trust
He is a wonderful God that will not disappoint us

No comments:

Post a Comment